Abstract
Oriṣa nla d’aro mẹtaO da’kan ni dudu,O da’kan ni pupa,O da’kan ni funfun.Dudu ni o rẹ mi,O o gbọdọ rẹ mi ni pupa.Dudu ni o rẹ mi,O o gbọdọ rẹ mi ni funfun,Iwa mi ni o kọ tete rẹNi kutukutu Ọbariṣa....
Published Version
Join us for a 30 min session where you can share your feedback and ask us any queries you have